A le ṣe atunṣe si Ofin yii ti isinmi (holiday) ba wa, tabi fun irorun ti gbogbo omo ẹgbẹ.
Maṣe gbagbe lati ṣe akiyesi awọn ọjọ wọnyi ninu kalẹnda rẹ ati pe ti o ko ba raye ni asiko naa, ranti lati se ayewo ipade na ninu ikanni #ipade lori slack.
Awọn ipade wa ni sisi fun ẹnikẹni ti o nifẹ lati tumọ WordPress si Yoruba.